ADUA IKORIRA GBIGBA OHUN ASAN
LASAN KAN GBO PE O LE MU KI IBI O
SEYAN
﷽
1
[ALLAHUMMA LAA TAIRA ILLA TAIRUK, WA LAA KHAIRA
lLLA KHAIRUK, WA LAA ILAAHA GAIRUK].
« Olohun kò si eye kan yato si eye Re, ati pe kò si
oore kan bi ko se oore Re, bee ni kò si oba kan ti o to
lati fi ododo josin fun yato si O >>.