ADUA TI I PA ESE TI ENIYAN DA NIBI TI O BA TI JOKOO RE

1

[SUBHAANAKA -L-LAHUMMA WA BI HAMDIK, ASH’HADU AN LAA ILAAHA ILLA ANT, ASTAGFIRUKA WA ATUUBU ILAIK]. « Mimo ni fun Iwo Olohun, ope si ni fun O, mo jeri pe kò si oba kan ti o leto si pe ki a fi ododo josin fun yato si O, mo n toro idarijin lodo Re, mo si n ronupiwada Io si odo Re >>.

Zaker copied