ADUA ENI TI O RI ENIKAN TI OLOHUN FI ADANWO KAN

1

[AL-HAMDU LI-L-LAHI –L-LADZEE AAFAANEE MIMMAA –B- TALAAKA BIHI WA FADH-DHALANEE ALAA KHA THEERIN MIMMAN KHALAQA TAFDHEELAA], « ope ni fun Olohun t’O ko mi la kuro ninu ohun ti o fi dan o wo, ti O si se ajulo fun mi lori opolope ninu awon eda ti O da ni ajule >>.

Zaker copied