ADUA TI ENI TI O GBEYAWO ATI ENI TI O RA ERANKO GUNGUN O SE

1

Ojise Olohun “ki ike ati oIa Olohun o maa ba A”so pe: « Nigba ti enikan yin ba fe obinrin kan, tabi o ra omo-odo “eru” kan ki o so pe:- [ALLAHUMMA INNEE AS’ALUKA KHAIRAHAA WA KHAIRA MAA JABALTAHAA ALAIHI, WA AUUDZU BIKA MIN SHARRIHAA WA SHARRI MAA JABALTAHAA ALAIHI] “Olohun mo n toro pe ki O se oore re fun mi ati oore ti O se adamo re le e lori, mo si n fi O wa isadi nibi aburu re ati aburu ti O se adamo re le e lori . Ati pe nigba ti enikan yin ba ra rakunmi kan ki o di oke ike eyin re mu ki o si wi iru awon gbolohun yii >>.

Zaker copied