ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA RI OSU

1

[ALLAHU AKBAR, ALLAHUMMA Al’ILLAHU ALAINAA BI -L- AMNI WA -L-IMAAN, WA -S-SALAAMATI WA -L-ISLAAM, WA -T-TAWFEEQI LIMAA TUHIBBU RABBANAA WA TARDHAA, RABBUNAA WA RABBUKA -L-LAH]. « Olohun l’0 tobi ju, Olohun je ki osu yii o le fun wa pelu ibale-okan ati igbagbo-ododo, ati alaafia ati igbafa fun Olohun Oba. ati konge Io sidi ohun ti Iwo Oluwa wa N te ti O si yonu si, Olohun ni Oluwa awa ati iwo [osu] >>.

Zaker copied