ADUA TI ENIYAN O SE NIGBA TI O BA FE
WO ILE-IGBONSE TABI AYE YOWU TI O TI
FE SE IGBONSE
﷽
1
[BISMI -L-LAH, ALLAHUMMA INNEE AUUDZU BIKA MINA -L-
KHUBUTHI WA -L-KHABAA’ITH].
« -Mo n wole- ni oruko Olohun, Mo sadi Iwo
Olohun kuro ni ode awon okunrin ati awon obinrin
esu >>