[INNA LI-L-LAHI MAA AKHADZA, WA LAHU MAA A'ATAA, WA KULLU SHAIN IN INDAHU Bl AJALIN MUSAMMAA, FALTASBlR WALTAHTASIB]. « Dajudaju ti Olohun ni gbogbo ohun ti O gba pada, Oun naa I’O si ni gbogbo ohun t’O jogun fun wa, ati pe gbogbo nnkan pata I’o ni asiko ti Olohun Oba da. fun un, tori naa se suuru, ki o si reti esan re lodo Olohun Oba >>. Ti eniyan ba si so pe: [A’ADZAMA -L-LAHU AJRAKA WA AH'SANA AZAA’AKA WA GAFARA LIMAYYITIK]. >. O dara.