ADUA ALAARE TI KO SI IRETI ATISEMI FUN UN MO

1

[ALLAHUMMA -G-FIR LEE WA -R-HAMNEE WA ALHIQNEE BI- R-RAFEEQI -L-A'ALAA]. >.

2

Nigba ti asiko iku Anabi wa “ike ati ola Olohun k‘o maa ba a de o bere si ni ti owo re mejeeji bo inu omi o si n fi owo mejeeji naa pa oju re; o si n so bayii pe: [LAA ILAAHA ILLA -L-LAHU INNA LILMAWTI LASAKARAAT]. >.

3

[LAA ILAAHA lLLA -L-LAHU WA –L-LAHU AKBAR, LAA ILAAHA lLLA -L-LAHU WAHDAH, LAA ILAAHA lLLA -L-LAHU WAHDAHU LAA SHAREEKA LAH, LAA |LAAHA ILLA -L-LAHU LAHU -L-MULKU WA LAHU -L-HAMD, LAA ILAAHA lLLA -L- LAHU WA LAA HAWLA WA LAA QUWWATA ILLA BI -L-LAH]. >.

Zaker copied