OLA TI N BE FUN SISE ABEWO ALAARE

1

Ojise Olohun “ike ati Ole Olohun k’o maa ba a So pe: « Nigba ti eniyan ba se abewo omo-iya re Musulumi ti n se aare, ori oju-ona Al-Janna —Ogba idera- ni yoo wa titi yoo fi jokoo “lode re”, nigba ti o ba si jokoo “lodo re” tan aanu Olohun yoo bo o, ati pe ti o ba se pe aaro kuu ni o se abewo yii si, awon Malaika egberun lona aadorin yoo maa sadua fun un titi ti yoo fi lele, bce ni ti o ba je pe irole ni o se abewo naa si awon Malaika egberun lona aadorin yoo maa se adua fun un titi yoo fi ji lowurc) >>.

Zaker copied