OHUN TI ENI TI O BA DESE KAN YOO WI
ATI OHUN TI YOO SE
﷽
1
Ojise Olohun ike ati oIa Olohun k’o maa ba
A”so pe:
« Eru Olohun kan kò ni i dese kan, ki o wa se
aluwala daadaa, ki o si dide ki raka meji, leyin naa ki
o toro aforijin lodo Olohun afi ki Olohun O se
aforijin fun un >>.