ADUA ATIRI GBESE SAN

1

[ALLAHUMMA AKFINEE BI HALAALIKA AN HARAAMIK, WA AGNINEE Bl FADHLIKA ANMAN SIWAAK]. « Iwo Olohun, to mi pelu ohun ti O se ni eto kuro nidi ohun ti O se leewo, si ro mi lore pelu oIa Re kuro ni odo elomiran yato si O ».

2

[ALLAHUMMA INNEE AUUDZU BIKA MINA -L-HAMMI WA -L- HAZAN, WA -L-AJ'ZI WA -L-KASAL, WA -L-BUKHLI WA -L- JUB'N, WA DAL’I -D-DAINI WA GALABATI -R-RIJAAL]. « Iwo Olohun, mo n sadi Re nibi aibale-okan ati ibanujc. ati ikaare ati oroju, ati ahun, ati ole. ati eru gbese, ati nibi ki gbese o bori mi, ati nibi ki awon eniyan o bori mi >>.

Zaker copied