ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA FE PADE OTA RE TABI ENI TI IJOBA N BE LOWO RE

1

[ALLAHUMMA INNAA NAJ’ALUKA FEE NUHUURIHIM WA NA’UUDZU BIKA MIN SHURUURIHIM]. « Iwo Olohun, a n fi O si ookan aya won -a n be O pe ki O ba ni di igba-aya won, ma je ki won o le de odo wa rara-, a si n sadi Re nibi awon aburu won ».

2

[ALLAHUMMA ANTA ADUDEE, WA ANTA NASEEREE, BIKA AJUUL, WA BIKA ASUUL, WA BIKA UQAATIL]. « Iwo Olohun ni Alafeyinti mi, Iwo ni Alaranse mi, Iwo ni n o fi maa ti ete ota danu, Iwo ni n o si fi bori won, Iwo ni n o fi maa ba won ja ».

3

[ASBUNAA -L-LAHU WA NI’IMA -l-WAKEEL]. « Olohun to wa, O si dara pupo ni Alafeyinti ».

Zaker copied