ADUA AIBALE-OKAN ATI IBANUJE

1

[ALLAHUMMA INNEE ABDUK, IBNU ABDIK, IBNU AMATIK. NAASIYATEE BI YADIK, MAADHIN FIYYA HUKMUK, ADLUN FIYYA QADHAA’UK, AS’ALUKA BI KULLI S'MIN HUWA LAKA SAMMAITA BIHI NAFSAK, AW ANZALTAHU FEE KITAABIK, AW ALLAMTAHU AHADAN MIN KHALQIK, AWI S’TA’ATHARTA BIHI FEE ILMI -L-GAIBI INDAK, AN TAJ'ALA - L-QUR’AANA -L-ADZEEMA RABEE’A QALBEE, WA NUURA SADREE, WA JALAA’A HUZNEE, WA DZAHAABA HAMMEE]. « Iwo Olohun, dajudaju eru Re ni mi, omo eru Re lokunrin, omo eru Re lobinrin, asoso mi n be ni owo Re, idajo Re n se le mi lori, akoole Re si se dogba lori mi, mo n be O pelu gbogbo oruko ti o je ti E. eyi ti O so ara Re, tabi eyi ti O so kale sinu tira Re. tabi eyi ti O fi mo enjkan ninu awon eda Re, tabi eyi ti o se wi pe Iwo nikan I’O mo on ninu imo ikoko ti o wa lodo Re, pe ki O se Al-Qur’aan alaponle ni itutu okan mi, ati imole igba-aya mi, ati isipaya ibanuje mi, ati olumu aibale-okan mi lo ».

2

[ALLAHUMMA INNEE AUUDZU BIKA MINA -L-HAMMI WA -L- HAZAN, WA –L-AJZI WA -L-KASAL, WA -L-BUKH'Ll WA -L- JUB’N, WA DHALA’l -D-DAINI WA GALABATI R-RIJAAL]. « Iwo Olohun, mo sadi Re nibi aibale-okan ati ibanuje, ati ikaare, ati oroju, ati ahun, ati ole, ati eru gbese, ati kuro nibi ki awon eniyan o bori mi ».

Zaker copied