OHUN Tl ENI TI O BA LALA RI ABURU NI OJU-OORUN YOO SE NIGBA TI O BA JI

1

Oluwaare yoo tu ategun ti ko ni ito ninu si apa alaafia re leemeta. 2- Yoo fi Olohun wa isadi kuro lodo esu ati aburu ohun ti o ri ni oju-oorun leemeta. 3- Ki ò ma se so ohun ti o ri ni oju-oorun re yii fun enikan kan rara. 4- Ki o yi egbe pada si apa miiran yato si eyi ti o wa lori re [nigba ti o lala naa].

Zaker copied