ADUA IBERU OJU-OORUN, ATI TI ENI TI BA N BE NINU ADANWO DIDAGBE

1

[AUUDZU BI KALIMAATI -L-LAHI -T-TAMMAATI MIN GADHABIHI WA IQAABIHI, WA SHARRI IBAADIHI, WA MIN HAMAZAATI -SH-SHAYAATEENI WA AN YAHDHURUUN]. « Mo n fi awon gbolohun Olehun ti o pe wa isadi nibi ibinu Re ati iya Re, ati ab aru awon eru Re, ati nibi awon iroyiroyi awon esu, ati kuro nibi ki won o wa si odo mi ».

Zaker copied