ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O RA YIRA-PADA LORU

1

[LAA ILAAHA ILLA -L-LAHU -L-WAAHIDU -L-QAHHAAR. RABBU -S-SAMAAWAATI WA -L-ARDHI WA MAA BAINAHUMAA -L-AZEEZU -L-GAFFAAR]. « Ko si eba kan ti o to lati fi ododo josin fun yate si Olohun Oba Okan-soso Olubori, Oluwa gbogbo awon sanma ati ile ati ohun ti n be laarin mejeeji Alagbara “t’o bori gbogbo nnkan Alaforijin ».

Zaker copied