AWON ADUA ORU ATI TI OSAN

1

AUUDZU BI -L-LAHI MlNA -SH-SHAITAANI -R-RAJEEM: [ALLAHU LAA ILAAHA ILLA HUWA -l-HAYYU -L- QAYYUUMU LAA TA’AKHUDZUHU SINATUN WA LAA NAWMUN LAHU MAA FEE -S-SAMAAWAATI WA MAA FEE -L-ARDHI MAN DZA -L-LADZEE YASHFAU INDAHU ILLA BI IDZNIHI YA’ALAMU MAA BAINA AIDIHIM WA MAA KHALFAHUM WA LAA YUHEETUUNA Bl SHAIN IN MIN ILMIHI ILLA Bl MAA SHAA’A WASIA KURSIYYUHU - S-SAMAAWAATI WA -L-ARDNA WA LAA YA’UUDUHU HIFDZUHUMAA WA HUWA -L-ALIYYU -L-ADZEEM].

2

Yoo ke okookan ninu awon Suura ti n bo wenyi ni Eemeta:- BISMI -L-LAHI -R-RAHMAANI -R-RAHEEM [QUL HUWA -L- LAHU AHAD *ALLAHU -S-SAMAD * LAM YALID WA LAM YUULAD * WA LAM YAKUN LAHU KUFWAN AHAD]. BISMI -L-LAHI -R-RAHMAANI -R-RAHEEM [QUL AUUDZU BI RABBI -L-FALAQ * MIN SHARRI MAA KHALAQ * WA MIN SHARRI GAASIQIN IDZAA WAGAB * WA MIN SHARRI -N- NAFAATHAATI FEE -L-UQAD * WA MIN SHARRI HAASIDIN IDZAA HASAD]. BISMI -L-LAHI -R-RAHMAANI -R-RAHEEM [QUL AUUDZU BI RABBI -N-NAAS * MALIKI –N-NAAS * ILAAHI -N-NAAS * MIN SHARRI -L-WASWAASI -L-KHANNAAS * AL-LADZEE YUWASWISU FEE SUDUURI -N-NAAS * MINA -L-JINNATI WA –N-NAAS].

3

[ASBAHNAA WA ASBAHA -L-MULKU LI -L-LAH, AL-HAMDU LI -L-LAH, LAA ILAAHA ILLA -L-LAHU WAHDAHU LAA SHAREEKA LAH, LAHU -L-MULKU WA LAHU -L-HAMDU WA HUWA ALAA KULLI SHAIN IN QADEER, RABBI AS'ALUKA KHAIRA MAA FEE HAADZA -L-YAWMI WA KHAIRA MAA BA’ADAH, WA AUUDZU BIKA MIN SHARRI MAA FEE HAADZA -L-YAWMI WA SHARRI MAA BA’ADAH, RABBI AUUDZU BIKA MIN ADZAABIN FEE —N-NAARI WA ADZAABIN FEE -L-QABR]. >.

4

[ALLAHUMMA BIKA ASBAHNAA, WA BIKA AMSAI’NAA, WA BlKA NAHYAA WA BIKA NAMUUT, WA ILAIKA -N- NUSHUUR}

5

[ALLAHUMMA ANTA RABBEE LAA ILAAHA ILLA ANT, KHALAQTANEE WA ANA ABDUK, WA ANA ALAA A'ADIKA WA WA'ADIKA MAA -S-TATA’AT, AUUDZU BIKA MIN SHARRI MAA SANA’ATU, ABUU’U LAKA BI-NI’IMATIKA ALAIYYA, WA ABUU'U LAKA BI-DZAMBEE FAGFIR’LEE FA- INNAHU LAA YAGFIRU —D-DZUUBA ILLA ANTA].

6

[ALLAHUMMA INNEE ASBAHTU USH'HIDUKA WA USH'HIDU HAMALATA ARSHIK, WA MALAAIKATAKA WA JAMI’EE’A KHALKIK, ANNAKA ANTA -L-LAHU LAA ILAAHA ILLA ANTA WAHDAKA LAA SHAREEKA LAK, WA ANNA MUHAMMADAN ABDUKA WA RASUULUK]; leemerin, « Iwo Olohun mo ji saye. mo n fi Iwo ati awon Malaika ti won ru aga-ola Re, ati awon Malaika Re yoku, ati gbogbo awon eda Re se eleri wi pe: Iwo ni Olohun Oba ti kò si Oba miiran ti o to lati fi ododo josin fun yato si O, ni Iwo nikan soso, kò si orogun kan fun O, ati pe Anabi Muhammad eru Re ni i se Ojise Re Si ni pelu >>.

7

[ALLAHUMMA MAA ASBAHA BEE MIN NI'IMATIN AW BI’AHADIN MIN KHALQIKA FAMINKA WAHDAKA LAA SHAREEKA LAK, FALAKA -L—HAMDU WA LAKA -SH- SHUKR]. « Iwo Olohun, odo Re nikan ni gbogbo idera ti o ba emi tabi eyi ti o ba okan ninu awon eru Re ji ti wa, ko si orogun fun O, eyin ni fun O, epe si ni fun O».

8

[ALLAHUMMA AAFINEE FEE BADANEE, ALLAHUMMA AAFINEE FEE SAM’1’EE, ALLAHUMMA AAFINEE FEE BASAREE, LAA ILAAHA ILLA ANT. ALLAHUMMA INNEE AUUDZU BIKA MINA -L-KUFR, WA FAQR, WA AUUDZU BIKA MIN ADZAABI -L-QABR, LAA ILAAHA ILLA ANT];leemeta. >.

9

[HASBIYA —L-LAHU LAA ILAAHA ILLA HUWA ALAIHI TAWAKKALTU WA HUWA RABBL -L-ARSHI -L-ADZEEM]; leemeje. « Olohun to mi, kò si oba kan ti o to lati fi ododo josin fun yate si I, Oun ni mo gbekele, Oun ni Oluwa Alaga o1a titobi ».

10

[ALLAHUMMA INNEE AS’ALUKA -L-AFWA WA -L-AAFIYATA FEE –D-DUNIYA WA -L-AAKHIRAH, ALLAHUMMA INNEE AS’ALUKA -L-AFWA WA -L-AAFIYATA FEE DEENEE WA DUNYAAYA WA AHLEE, WA MAALEE, ALLAHUMMA -S-TUR AWRAATEE, WA AAMIN RAW’AATEE, ALLAHUMMA - H’FADZNEE MIN BAINI YADAYYA, WA MIN KHALFEE. WA AN YAMEENEE, WA AN SHIMAALEE, WA MIN FAWQEE, WA AUUDZU BI ADZAMATIKA AN UGTAALA MIN TAHTEE], « Iwo Olohun, mo n toro amojukuro ati alaafia lodo Re ni aye ati lorun, Olohun, mo n toro pe ki o se amojukuro ati alaafia fun mi ni orun mi ati ni aye mi ati lara ebi mi, ati owo mi. Olohun ba mi gbe awon alebu mi pamo, fi mi lokan bale nibi awon ifoya mi “le won jinna si mi , Iwo Olohun, so mi ni iwaju mi, ati leyin mi, ati lapa Otun mi, ati lapa alaafia mi, ati ni oke mi, mo si n fi titobi Re wa isadi nibi ki a yo mi pa lati isale mi >>.

11

[ALLAHUMMA AALIMA -L-GAIBI WA -SH-SHAHAADATI FAATIRA -S-SAMAAWATI WA -L-ARDH, RABBA KULLI SHAIN IN WA MALEEKIHI, ASH’HADU AN LAA ILAAHA ILLA ANT, AUUDZU BIKA MIN SHARRI NAFSEE, WA MiN SHARRI –SH- SHAITAANI WA SHlRKIHI ‘WA SHARAKIHI’, WA AN AQTARIFA ALAA NAFSEE SUU’AN, AW AJURRAHU ILAA MUSLIM]. « Iwo Olohun Olumo ikoko ati gbangba, Olupileda awon sanma ati ile, Oluwa gbogbo nnkan ati Olowo won, mo jeri pe ko si oba kan ti o to lati fi ododo josin fun yato si O, mo n fi O wa isadi kuro nibi aburu ara mi, ati nibi aburu esu, ati isebo si Olohun ti i maa n pe ni lo sidi re “tabi ati etc re , ati kuro nibi kj n se ori ara mi ni aburu, tabi ki n fa a 1o ba Musulumi ».

12

[BISMI -L-LAHI -L-LADZEE LAA YADHURRU MA'A -S-MIHI SHAI’UN FEE -L-ARDHI WA LAA FEE -S-SAMAAI WA HUWA - S-SAMEE’U -L-ALEEM]; leemeta. >.

13

[RADHEETU BI -L-LAHI RABBAN, WA BI –L-ISLAAMI DEENAN, WA BI’MUHAMMADIN SALLA -L-LAHU ALAIHI WA -S- SALLAMA NABIYYAN]; leemeta. >.

14

[YAA HAYYU YAA QAYYUUMU BI’RAHMATIKA ASTAGEETHU ASLIH LEE SHA’ANEE KULLAHU WA LAA TAKILNEE ILAA NAFSEE TARFATA AIN]. « Iwo Oba Alaaaye! Iwe Oba Oludaduro! -ti kò bukata enikan ti gbogbo nnkan si n bukata Re-, aanu Re ni mo n fi n wa iranlowo, ba mi tun gbogbo oro mi se, ma se da mi dara mi ni odiwon iseju akan >>.

15

[ASBAHNAA WA ASBAHA -L-MULKU LI -L-LAHI RABBI -L- AALAMEEN, ALLAHUMMA INNEE AS’ALUKA KHAIRA HAADZAA -L-YAWM, FAT’HAHU, WA NASRAHU, WA NUURAHU, WA BARAKATAHU, WA HUDAAHU, WA AUUDZU BIKA MIN SHARRI MAA FEEHI WA SHARRI MAA BA’ADAH]. « A ji saye, akoso naa si ji fun Olohun Oba gbogbo eda, Iwo Olohun mo n toro oore oni lodo Re; isegun re, ati aranse re, ati imole re. ati oore re. ati imona re, mo si n sadi Re nibi aburu ohun ti n be ninu re ati aburu ohun ti n be leyin re >>.

16

[ASBAHNAA ALAA FITRATI -L-ISLAM WA ALAA KALIMATI - L- IKHLAAS, WA ALAA DEENI NABIYYINAA MUHAMMADIN SALLA -L-LAHU ALAIHI WA -S-SALLAM, WA ALAA MILLATI ABEENAA IBRAAHIMA HANEEFAN MUSLIMAN WA MAA KAANA MINA -L-MUSHRIKEEN].

17

[SUBHAANA -L-LAHI WA Bl HAMDIHI]; ni igba ogorun. >.

18

[LAA ILAAHA ILLA -L-LAHU WAHDAHU LAA SHAREEKA LAH, LAHU AL-MULKU WA LAHU -L-HAMD, WA HUWA ALAA KULLI SHAIN IN QADEER]; leemewa tabi leekan nigba ti oroju ba n seyan. « Kò si oba kan ti o to lati fi ododo josin fun yato si Olohun nikan soso, kò si orogun kan fun Un, Oun l’O ni o1a ati ope, Oun si ni Alagbara lori gbogbo nnkan ».

19

[LAA ILAAHA lLLA -L-LAHU WAHDAHU LAA SHAREEKA LAH. LAHU -L-MULKU WA LAHU -L-HAMD, WA HUWA ALAA KULLI SHAIN IN QADEER]; ni igba Ogorun nigba ti eniyan ba ji saye. « Kò si oba kan ti o to lati fi ododo josin fun yato si Olohun nikan soso, kò si orogun kan fun Un, Oun l’o ni ijoba ati ope, Oun si ni Alagbara lori gbogbo nnkan ».

20

[SUBHAANA -L-LAHI WA Bl HAMDIHI: ADADA KHALQIHI, WA RIDHAA NAFSIHI, WA ZINNATA ARSHIHI WA MIDAADA KALIMAA TIHI] leemeta; nigba ti eniyan ba ji saye. « Mimo ni fun Olohun, ope ni fun Un: Ni onka awon eda Re, ati ni odiwon iye ti O yonu si, ati osunwon aga o1a Re, ati iye tada awon oro Re ».

21

[ALLAHUMMA INNEE AS’ALUKA ILMAN NAAFIAN, WA RIZQAN TAYYIBAN, WA AMALAN MUTAQABBALAN]; nigba ti O ba ji saye.

22

[ASTAGFIRU -L-LAHA WA ATUUBU ILAIHI]; nigba ogorun lojumo. « Mo n toro aforijin lodo Olohun, mo si n ronupiwada lo si odo Re ».

23

[ALLAHUMMA SALLI WA SALLIM ALAA NABIYYINAA MUHAMMAD]; leemewa. « Iwo Olohun, se ike ati ige fun Anabi wa Muhammad ».

Zaker copied