ADUA TI ENIYAN O SE LEYIN ATAYA SIWAJU K1 O TOO SALAMA

1

[ALLAHUMMA INNEE AUUDZU BIKA MIN ADZAABI -L-QABR, WA MIN ADZAABI JAHANNAM, WA MIN FITNATI -L- MAHYAA WA -L-MAMAAT, WA MIN SHARRI FITNATI -L- MASEEHI -D-DAJJAAL]. « Mo n fi Iwo Olohun wa isadi nibi iya saare, ati nibi iya ina jahannama, ati nibi amiwo isemi ati ti iku. ati nibi aburu arito Maseeh Ad-Dajjaal “opuro olojukan” >>.

2

[ALLAHUMMA INNEE AUUDZU BIKA MIN ADZAABI -L-QABR, WA AUUDZU BIKA MIN FITNATI -L-MASEEH| D-DAJJAAL, WA AUUDZU BIKA MIN FITNATI -L-MAHYAA WA -L- MAMAAT, ALAHUMMA INNEE AUUDZU BIKA MINA -L- MA’ATHAMI WA -L-MAGHAM]. « Mo n fi Iwo Olehun wa isadi nibi iya saare, ati nibi arito Maseeh Ad-Dajjaal “opuro olojukan”, mo si n fi O wa isadi nibi amiwo isemi ati ti iku, Olohun mo n fi O wa isadi nibi ese ati gbese >>.

3

[ALLAHUMMA INNEE DZALMTU NAFSEE DZULMAN KHATHEERAN, WA LAA YAGFIRU DZUNUUBA ILLA ANTA FAGFIR LEE MAGFIRATAN MIN INDIK, WA -R-HAMNEE INNAKA ANTA –L-GAFUURU -R-RAHEEM]. « Dajudaju Iwo Olohun, mo ti se abosi fun ori ara mi ni abosi ti o tobi, enikan ki i si se aforijin ese fun ni yato si O, se aforijin fun mi ni aforijin kan lati odo Re, k’O si ke mi, dajudaju Iwo ni Alaforijin Alaaanu».

4

[ALLAHUMMA -G-FIR LEE MAA QADDAMTU, WA MAA AKH- KHARTU, WA MAA ASRARTU, WA MAA A’ALANTU, WA MAA ASRAFTU, WA MAA ANTA A’ALAMU BIH| MINNEE, ANTA –L-MUQQADIM,WA ANTA -L-MUAKHIR, LAA ILAA ILLA ANT]. >.

5

[ALLAHUMMA A’INNEE ALAA DZIKRIKA WA SHUKRIKA WA HUSNI IBAADATIK]. >.

6

[ALLAHUMMA INNEE AUUDZU BIKA MINA -L-BUKH’L, WA AUUDZU BIKA MINA -L-JUBUN, WA AUUDZU BIKA MIN AN URADDA ILAA ARDZALI -L-UMUR, WA AUUDZU BIKA MIN FITNATI -D-DUNIYAA WA ADZAABI -L-QABR]. « Mo sadi Iwo Olohun nibi ahun, ati nibi o1e, ati nibi ki n je eni ti a o da pada si eyi ti o buru ju njnu ogbo, mo si n fi O wa isadi nibi amiwo ile-aye ati nibi iya saare >>.

7

[ALLAHUMMA INNEE AS'ALUKA -L-JANNAH, WA AUUDZU BIKA MINA -N-NAAR]. « Mo n toro Al-janna -ogba idera- lode Iwo Olohun, mo si n sadi Re nibi ina ».

8

[ALLAHUMMA BI’ILMIKA –L-GAlBA WA QUDRATIKA ALAA –L- KHALQI AHYINEE MAA ALIMTA -L-HAYAATA KHAIRAN LEE, WA TAWAFFANEE IDZAA ALIMTA -L-WAFAATA KHAIRAN LEE, ALLAHUMMA INNEE AS’ALUKA KHASHYATAKA FEE -L- GAIBI WA -SH-SHAHAADAH, WA ASU’ALUKA KALIMATA -L- HAQQI FEE -R-RIDHAA WA -L-GADHAB, WA AS'ALUKA -L- QASDA FEE -L-GINAA WA -L-FAQR, WA AS’ALUKA NA’I’EEMAN LAA YANFAD, WA AS’ALUKA QURRATA AININ LAA TANQATIU, WA AS'ALUKA -R-RIDHAA BA'ADA –L- QADAA. WA AS’ALUKA BARDA -L-l ISHI BA’ADA -L-MAW’T, WA AS’ALUKA LADZATA N-NADZARI ILAA WAJHIKA WA SH-SHAWQA ILAA LIQAA'IKA FEE GAIRI DHARRAA’A MUDHIRRATIN WA LAA FITNATIN MUDHILLATIN, ALLAHUMMA ZAYYlNNAA Bl ZEENATI -L-IMAANI WA -J— ALNAA HUDAATAN MUHTADEEN]. « Iwe Olohun mo n fi imo ti O ni nipa ikoko ati agbara Re lati da eda be O pe ki O je ki n maa semi lopin igba ti O ba mo wi pe isemi l’o ni oore ju fun mi, ki o si pa mi nigba ti O ba mo wi pe iku l’o ni oore ju fun mi, Olohun mo n toro pe ki O se mi ni eni ti yoo maa paya Re ni ikoko ati ni gbangba, mo si n toro pe ki O maa fun mi ni ododo so ni asiko idunnu ati ibinu, mo si n tore pe ki O fun mi ni iwontunwonsi se ni igba ti mo ba wa ninu oro ati nigba ti mo ba wa ninu aini, mo si n toro awon idera ti ki i tan lodo Re, mo si n toro itutu oju ti ki I ja lodo Re, mo si n toro pe ki O fun mi ni iyonu leyin akosile, mo si n toro pe ki O fun mi ni isemi ti o rorun se leyin iku, mo si n toro lodo Re pe ki o fun mi ni adun wiwo oju Re. ati ijeran atipade Re laisi isoro ti i ni ni lara, tabi amiwo ti i si ni lona, Olohun se wa loso pelu oso igbagbo-ododo “Imaani” , se wa ni olumona ti i fi ni mona >>.

9

[ALLAHUMMA INNEE AS'ALUKA YAA ALLAHU BI’ANNAKA - L-WAAHIDU -L-AHADU S-SAMADU -L-LADZEE LAM YALID WA LAM YUULAD WA LAM YAKUN LAHU KUFWAN AHAD, AN TAGFIRA LEE DZUNUUBEE INNAKA ANTA -L-GAFUURU - R-RAHEEM].

10

[ALLAHUMMA INNEE AS’ALUKA BI’ANNA LAKA -L-HAMDU LAA ILAAHA ILLA ANTA WAHDAKA LAA SHAREEKA LAK, AL-MANNAAN, YAA BADEE’A -S-SAMAAWAATI WA –L- ARDH, YAA DZAL JALAALI WA -L-IKRAAM, YAA HAYYU YAA QAYYUUM INNEE AS’ALUKA -L-JANNATA WA AUUDZU BIKA MINA -N-NAAR]. >.

11

[ALLAHUMMA INNEE AS'ALUKA BI’ANNEE ASH'HADU ANNAKA ANTA -L-LAHU LAA ILAAHA ILLA ANT, -AL-AHADU -S-SAMADU -L-LADZEE LAM YALID WA LAM YUULAD, WA LAM YAKUN LAHU KUFWAN AHAD].

Zaker copied