ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA T’O BA FI ORI KANLE NI QKAN NINU AWON AYE TI A TI MAA N FI ORI KANLE NIGBA TI A BA N KEAL- OUR’AAN ALAPONLE

1

[SAJADA WAJHEE LI -L-LADZEE KHALAOAHU, WA SHADDA SAM'A’HU WA BASARAHU BI HAWLIHI WA QUWWATIHI, ‘FATABAARAKA –L-LAHU AH'SANA —L-KHAALIQEEN ]. « Oju mi teriba fun Eni ti O da a, ti O si la eti ati oju iriran re si ara re pelu ogbon ati agbara Re, “Ibukun ni fun Olohun Oba ti O da awon eda Re ni ona ti o dara julo >>.

2

[ALLAHUMMA -K—TUB’LEE BIHAA INDAKA AJRAN, WA DHA’A ANNEE BIHAA WIZRAN, WA -J-ALHAA LEE INDAKA DZUKHRAN, WA TAQABBALHAA MINNEE KAMAA TAQABBAL TA MIN ABDIKA DAA’UUD]. « Olehun ko esan re sile fun mi lodo Re, ki O si ba mi fi pa Okan ninu awon ese mi re, ki O si se e fun mi ni ere ti a gbe pamo si odo Re, wa gba a lesin fun mi gege bi O ti se gba a lesin fun eru Re Anabi Daa’uud >>.

Zaker copied