ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA FI 0RI KANLE

1

[SUBHAANA RABBIYA -L-A'ALAA]; leemeta. « Mimo ni fun Oluwa mi Oba ti O ga ju >>.

2

[SUBHAANAKA -L-LAHUMMA RABBANAA WA Bl HAMDIKA- L-LAHUMMA –G-FIR’LEE]. >.

3

[SUBBUUHUN, OUDDUUSUN RABBU -L-MALAAIKATI WA -R- RUUH]. .

4

[ALLAHUMMA LAKA SAJADTU, WA BIKA AAMANTU, WA LAKA ASLAMTU, SAJADA WAJHEE LI -L—LADZEE KHALAQAHU, WA SAWWARAHU, WA SHAQQA SAM’A’HU, WA BASARAHU, TABARAKA -L-LAHU AH'SANA -L- KHAALIQEEN]. >.

5

[SUBHAANA DZEE –L-JABARUUT, WA –L-MALAKUUT, WA -L- KIBRIYAA. WA -L-ADZAMAH]. .

6

[ALLAHUMMA -G-FIR'LEE DZAMBEE KULLAHU, DIQQAHU WA JILLAHU, WA AWWALAHU WA AAKHIRAHU, WA ALAANIYYATAHU, WA SIRRAHU]. « Olohun dari gbogbo awon ese mi jin mi, eyi ti o we ninu won, ati eyi ti o tobi, akoko won, ati eyi ti o gbeyin, eyi ti mo da ni gbangba, ati eyi ti mo se ni ikoko >>.

7

[ALLAHUMMA INNEE AUUDZU BI RIDHAAKA MIN SAKHATIK. WA Bl MU’AAFAATIKA MIN UQUUBATIK, WA AUUDZU BIKA MINKA LAA UH’SEE THANAA’AN ALAIKA ANTA KAMA ATH'NAITA ALAA NAFSIK]. « Iwo Olohun mo n fi iyonu Re wa isadi kuro nibi ibinu Re, mo si n fi amojukuro Re wa isadi kuro nibi iya Re, mo si n fi O wa isadi ni odo ara Re, kò si bi mo ti se le yin O ti o le da gege bi O ti se yin ara RE».

Zaker copied