[SAMIA -L-LAHU LIMAN HAMIDAH].
[RABBANAA WA LAKA -L-HAMD, HAMDAN KHATHEERAN TAYYIBAN MUBAARAKAN FEEH]. « Oluwa wa. tiE ni gbogbo ope i se, ni ope ti o dara ti O se ibukun fun >>.
[MIL’A -S-SAMAAWATI WA MIL’A -L-ARDHI WA MAA BAINAHUMAA, WA MIL’A MAA SHI’ITA MIN SHAI'IN BA’AD, AHLA THANAA‘I WA -L-MAJD. AHAQQU MAA QAALA -L- ABD, WA KULLUNAA LAKA ABD: LAA MAANIA LIMAA A’ATAITA, WA LAA MU'UTIYA LIMAA MANA'ATA, WA LAA YANFAU DZA -L-JADDI MINKA -L-JADD]. « Ni ope ti o kun gbogbo awon sanma ati ile ati ohun ti n be laarin mejeeji, Ii o si tun kun ohun miiran ti O ba fe leyin awon wenyi, Iwo ni Oba eyin ati ogo; eyi ti o to ju ninu ohun ti eru Olohun wi –bee ni eru Re ni gbogbo wa je- ni pe: Kò si enikan ti o le di ona ohun ti O ba pe ni teni, kò si si enikan ti o le fun ni ni ohun ti O ko lati fun ni, ati pe oro Qloro kan kò le e se e ni anfaani kankan rara lodo Re ».