ADUA TI ENIYAN YOO SE NI RUKU

1

[SUBHAANA RABBIYA –L-ADZEEM]; leemeta.

2

[SUBHAANAKA -L-LAHUMMA RABBANAA WA Bl HAMDIKA- L-LAHUMMA -G-FIR LEE]. >.

3

[SUBBUUHUN QUDDUUSUN, RABBU -L-MALAAIKATI WA -R- RUUH] « Amo-kuro-ninu-gbogbo-aidaa, Oni-mimo Onibukun, Oluwa awon Malaika ati Jibreel ».

4

[ALLAHUMMA LAKA RAKA'A’TU, WA BIKA AAMANTU, WA LAKA ASLAMTU, KHASHI’A LAKA SAM’I’EE, WA BASAREE, WA MUKKHEE, WA ADZMEE, WA ASABEE, WA MAA -S- TAQALLA BIHI QADAMEE]. « Iwe Olohun ni mo te -ruku- fun. Iwo si ni mo gbagbg lododo, Iwe ni mo gbafa fun, eti mi, oju mi, opolo mi, eegun ara mi, isan mi, ati ohun ti ese mi gbe duro gbogbo won ni won teriba fun Iwo Olohun>>.

5

[SUBHAANA DZEE -L-JABARUUT, WA –L-MALAKUUT, WA –L- KIBRIYAA, WA -L-ADZAMAH]. «Mimo ni fun Oba Olubori, Oni-ijoba, ati motomoto, ati titobi ».

Zaker copied