AWON OHUN Tl ENIYAN YOO MAA WI NIGBA TI WON BA N PERUN

1

Eniyan yoo maa wi iru ohun ti oluperun n wi yato si wi pe nigba ti o ba so pe: [HAYYA ALA S-SALAAH]. ati [HAYYA ALA -L-FALAAH]. ohun ti eniyan yoo wi leyin ekini keji won ni: [LAA HAWLA WA LAA QUWWATA ILLA Bl -L-LAH].

2

Leyin ti oluperun ba wi awon gbolohun ijeri mejeeji [ti i se: ASH’HADU AN lAA ILAAHA ILLA -l- LAH]. ati [ASH’HADU ANNA MUHAMMADAN RASUULU - L-LAH] tan. ti eniyan naa si ti wi i tele e leyin gege bi o ti wi i. eniyan o So pc: [RADHEETU BI-L-LAHI RABBAN, WA BI MUHAMMADIN RASUULAN, WA Bl –L-ISLAMI DEENAN]. « M0 gba Olohun ni Oluwa, mo si gba Muhammad ni ojise. mo si gba Islam lesin >>.

3

Leyin naa ni eniyan o wa wi awon gbolohun ti n bo wonyi: [ALLAHUMMA RABBA HAADZIHI -D-DA’AWATl -T- TAAMMAH, WA -S-SALAATI -L-QAA’IMAH, AATI MUHAMMADAN AL-WASEELATA WA L-FADHEELAH, WAB’ATH’HU MAQAAMAN MAHMUUDANI -L-LADZEE WA ADTAH, INNAKA LAA TUKHLIFU -L-MEE’AAD]. >.

4

Leyin eleyii eniyan o maa toro gbogbo ohun ti n fe ni oore laarin asiko ti n be leyin irun pipe si igba ti won yoo gbe irun duro, tori pe Olohun ki I ko adua si eru RE lenu ni asiko naa.

5

Leyin ti won ba perun tan eniyan o se asalatu fun Anabi wa ike ati ola Olohun k'o maa ba a .

Zaker copied