BAWO NI ANABI WA IKE ATI OLA OLOHUN
K’O MAA BA A TI I MAA N SE TESBEEH —
AFOMO-
﷽
1
Egbawa-oro yii wa lati odo Abdullahi Ibn
Amr, “ki Olohun O yonu si awon mejeeji”, o ni:
« Mo ri Anabi “ike ati ola Olohun k’o maa ba a ti n
fi awon koko awon omo-ika owo re otun ka
[gbolohun] afomo “Al-Tesbeeh” ti n se >>.