OLA TI N BE FUN GBOLOHUN “SUBHAANA -L-LAH” ATI “AL-HAMDU LI L-LAH" ATI “LAA ILAAHA ILLA -L-LAH” ATI “ALLAHU AKBAR”

1

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k’o maa ba a so pe: >.

2

Ojise Olohun “ki ike ati ola Olohun o maa ba a tun so pe: >.

3

Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a tun so pc: >.

4

Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k‘o maa ba a”tun so pe:

5

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k’o maa ba a” tun so pe: .

6

Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a” so pe: « Enikeni ti o ba so pe: [SUBHAANA -L-LAHI -L-ADZEEMI WA BI HAMDIHI] a o gbin igi debiinu kan fun un sinu Al-Janna “ogba idera ».

7

Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a” tun so pe: « Iwo Abdullahi omo Qais, o yoo wa je ki n toka si pepe oro kan ninu awon pepe oro Al-Janna -ogba idera- fun o bi? ». Ni mo ba ni: Bee ni iwo Ojise Olohun, o ni: So pe:[LAA HAWLA WA LAA QUWWATA ILLA BI -L-LAH] ».

8

Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a” tun so pe:

9

Ara-oko kan wa ba Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a o si so pe: Ko mi ni oro kan ti n o maa so; Ojise Olohun ni: « Maa so pe: [LAA ILAAHA ILLA -L-LAHU WAHDAHU LAA SHAREEKA LAH, ALLAHU AKBAR KABEERAN, WA -L-HAMDU LI-L-LAHI KATHEERAN,SUBHAANA -L-LAHI RABBI -L-AALAMEEN, LAA HAWLA WA LAA QUWWATA ILLA BI -L-LAHI -L-AZEEZI -L- HAKEEM] >. Oni-beere ni: Ti Oluwa ni gbogbo awon gbolohun wonyi i se, ewo ni temi ?, Ojise Olohun ni:

10

>.

11

Ojise Olohun “ki ike ati ola Olohun o maa ba a so pe: « Dajudaju eyi ti o lola ju ninu adua ni: [AL-HAMDU LI- L-LAH] -ti o tumo si pe-: “Gbogbo ope ti Olohun Oba ni i se”. Eyi ti o si lola ju ninu iranti “AI-dzikr” ni: [LAA ILAAHA ILLA –L-LAH] –itumo -: “Ko si oba kan ti o to lati josin fun lododo yato si Olohun Oba >>.

12

Ojise Olohun ike ati oIa Olohun k'o maa ba a so pe: « Awon daadaa ti won maa n seku [fun eniyan] ni: [SUBHAANA -L-LAH, WA -L-HAMDU Ll-L-LAH, WA LAA ILAAHA ILLA -L-LAH, WA -L-LAHU AKBAR, WA LAA HAWLA WA LAA QUWWATA ILLA BI-L-LAH] “Mimo ni fun Olohun Oba. ati pe ko si oba kan t’o to lati sin lododo afi Olohun Oba, ati pe Olohun Oba I’O tobi ju, bee ni kò si Ogbon kan kò si si agbara kan leyin Olohun >>.

Zaker copied