ITORO AFORIJIN ATI IRONUPIWADA

1

Ojise Olohun “ike ati Qla Olohun k'o maa ba a” so pe: « Mo fi Olohun bura pe emi a maa toro aforijin lodo Olohun, mo si maa n se ironupiwada Io si odo Re ju igba aadorin Io ni ojumo kan ».

2

Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a” tun so pe: « Eyin eniyan e maa ronupiwada Io si odo Olohun Oba, tori pe dajudaju emi gan-an alara a maa ronupiwada lo si odo Re ni igba Ogorun ni ojumo kan ».

3

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k’o maa ba a” tun so pe:

4

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k‘o maa ba a tun so pc: « Igba ti Oluwa Oba maa N sunmo cru Re ju ni ikeyin aarin oru, tori naa ti o ba ses se fun o lati je eni ti yoo maa se AI-dzikr “iranti Olohun Oba ni asiko naa se bee ».

5

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k‘o maa ba a” tun so pe: >.

6

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k‘o maa ba a” tun so pe: « Dajudaju “igbagbd” a maa bo mi lokan -ni eekanlaare lati se iranti OIohun—, ati pe dajudaju emi a maa toro idarijin lodo Olohun ni igba ogorun lojoojumo ».

Zaker copied