OHUN TI ENIYAN YOO WI NIGBA TI O BA FE DURAN TABI YOO GUNRAN

1

[BISMI -L-LAHI WA -L-LAHU AKBAR, ALLAHUMMA MINKA WA LAKA, ALLAHUMMA TAQABBAL MINNEE]. « Mo bere ni oruko Olohun, Olohun l’O tobi ju, Iwo Olohun, odo Re I’o ti wa, ati pe tiE ni i se, Iwo Olohun gba a “lesin” fun mi ».

Zaker copied