ADUA TI ENI TI N BERU KI OUN O MA FI OJU OUN BA NNKAN KAN JE YOO SE

1

Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a” so pe: « Nigba ti enikan ninu yin ba ri nnkan kan ti o jo o loju lodo omo-iya re, tabi ni ara re. tabi lara owo re, ki o sadua fun un pe ki Olohun O ba a fi oore si i, nitori pe dajudaju ododo ni oju i se ».

Zaker copied