SISE IRANTI OLOHUN NI AL-MASH’ARU-L- HARAAM [NI MUZDALIFAH]

1

« Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a gun AI-qaswaa rakunmi re-, “lati Arafa” titi o fi de Al- Mash’aru-l-Haraam “ni Muzdalifah”, o si d’oju ko Al-qibla “iha Kaaba”, “O si bere si pe Olohun, o si n se agbega Re -ALLAHU AKBAR-, o si n wi gbolohun pe kò si oba kan ti o to lati fi ododo josin fun yato si I —LAA ILAAHA ILLA -L-LAH-, 0 si n se E laaso , kò si yee be ni iduro titi ti ile fi mo kedere, o si gbera kuro nibe siwaju ki oorun o too yo ».

Zaker copied