ADUA QJQ ARAFA

1

Anabi “ike ati ola Olohun k’o maa ba a” so pe: « Eyi ti o loore ju ninu adua ni adua ojo Arafa, ati pe ohun ti o loore ju ti emi ati awon anabi ti won siwaju mi wi “ni ojo yii ni: [LAA ILAAHA ILLA -L-LAHU WAHDAHU LAA SHAREEKA LAH, LAHU -L- MULKU WA LAHU -L-HAMD, WA HUWA ALAA KULLI SHAIN IN QADEER] “Kò si oba kan ti o to lati fi ododo josin fun yato si Olohun nikan soso, kò si orogun fun Un. Oun l’O ni gbogbo akoso ati ope, Oun si ni Alagbara lori gbogbo nnkan”>>.

Zaker copied