ADUA TI ENIYAN YOO MAA SE LAARIN ORIGUN YAMAANI ATI TI OKUTA DUDU [AL-HAJARU-L-ASWAD]

1

[RABBANAA AATINAA FEE -D-DUNIYAA HASANATAN WA FEE -L-AAKHIRATI HASANATAN WA QINAA ADZAABA -N- NAAR]. « Oluwa wa, fun wa ni daadaa ni ile-aye. si fun wa ni daadaa ni ile-igbeyin, wa so wa nibi iya ina ».

Zaker copied