OHUN TI MUSULUMI YOO SO NIGBA TI WON BA FO O MO [TI WON BA YIN lN]

1

[ALLAHUMMA LAA TU’AAKHIDZNEE BI MAA YAQUULUUN. WA G'FIR LEE MAA LAA YA’ALAMUUN, WA ‘J’ALNEE KHAIRAN MIMMAA YADZUNNUUN]. « Olohun, dakun ma se fi ohun ti won n wi je mi niya, si se aforijin fun mi Iori ohun ti won kò mo “nipa mi”, ki O si je ki n dara ju bi won ti n lero lo ».

Zaker copied