Ojise Olohun “ki ike ati oIa Olohun o maa ba a” so pe : [ALLAHUMMA FA-AYYUMAA MU’UMlNIN SABABTUHU FA-J- AL DZAALIKA LAHU OURBATAN ILLAIKA YAWMA -L- QIYAAMAH]. « Iwo Olohun! gbogbo olugbagbe-ododo ti mo bu ri je ki eebu naa o je ohun ti yoo mu un sun mo O ni ojo igbende >>.