ADUA TI A O SE NIGBA TI A BA GBO GBIGBO AJA LORU

1

Ojise Olohun “kj ikc ati ola Olohun o maa ba a” so pe: « Nigba ti e ba gbo gbigbo awon aja ati kike awon ketekete ni oru, e maa fi Olohun wa isadi kuro ni odo won, nitori pe dajudaju awon n ri ohun ti eyin ki i ri ».

Zaker copied