ADUA TI A O SE NIGBA TI AKUKO BA KO, ATI NIGBA TI KETEKETE BA KE

1

Ojise Olohun “ki ike ati ola Olohun o maa ba a” se pe: « Nigba ti e ba gbo kike awon akuko e maa toro lodo Olohun pe k’O fun yin ninu oore Re, nitori pe dajudaju Malaika kan ni won ri; nigba ti e ba si gbo igbe ketekete e maa fi Olohun wa isadi kuro ni odo csu, nitori pe dajudaju esu kan ni o ri ».

Zaker copied