BI A O TI DA ALAIGBAGBQ [KEFERI] LOHUN NIGBA TI O BA SALAMA SI WA

1

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k’o maa ba « Ti awon oni-tira “awon Yahudi tabi awon Nasaara -awon alagbelebu-“ ba salama si yin e da won lohun pe: [WA ALAIKUM] ».

Zaker copied