TITAN SALAMA [KIKI ARA ENI NI TI OLA] KA

1

Ojise Olohun “ki ike ati oIa Olohun o maa ba a” so pe: « E kò ni i wo Al-Janna -ogba idera- titi ti e o fi ni igbagbo-ododo, ati pe e ko ni i ni igbagbo-ododo titi ti e o fi feran ara yin, nje e o yoo wa je ki n toka si nnkan kan fun yin ti o se wi pe ti e ba se e e o nife ara yin bi?; e maa tan salama “kiki ara eni ni ti oIa” ka laarin yin >>.

2

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k’o maa ba a” so pe:

3

Egbawa-oro yii wa lati odo Abdullahi lbn Umar “Olohun Oba k’o yonu si awon mejeeji” o ni: Okunrin kan bi Anabi “ki ike ati ola Olohun o maa ba a” leere pe: Islam wo I’o loore ju?; Ojise Olohun si da a lohun pe: « Ki o maa fun [awon eniyan] ni ounje je, ki o si maa salama si eni ti o mo ati eni ti o kò mo >>.

Zaker copied