OLA TI N BE FUN SISE ASALATU [TITORO IKE ATI IGEI FUN ANABI WA IKE ATI OLA OLOHUN K’O MAA BA A

1

Ojise Olohun “ki ike ati oIa Olohun o maa ba a” so pe: >.

2

Ojise Olohun “ike ati Qla Olohun k’o maa ba a tun so pe: « E kò gbodo so saare mi di ohun ti e o maa se odun fun, e si maa se asalatu fun mi, nitori pe dajudaju asalatu yin yoo maa de ode mi lati ibikibi ti e ba wa >>.

3

Ojise Olohun “ike ati ola Qlohun k’o maa ba a” tun so pe: « Eni ti won daruko mi Iode re ti kò se asalatu fun mi ni ahun >>.

4

Ojise Olohun “ike ati ola Olohun k’o maa ba a” tun so pe: « Dajudaju Olohun Oba ni awon Malaika arinkaye kan lori ile ti won o maa jise kiki salama” ti awon ije mi ba n ki mi fun mi >>.

5

Ojise Olohun “ike ati oIa Olohun k’o maa ba a” tun so pe: « Enikan kò ni i salama si mi afi ki Olohun O da emi mi pada fun mi titi ti n o fi dahun kiki ti o ki mi >>.

Zaker copied