Yoo maa gbc Olohun tobi -ALLAHU AKBAR- leerneta, ni gbogbo igba ti o ba wa lori aye giga, leyin naa ni yoo wa so pe: [LAA ILAAHA ILLA -L-LAHU WAHDAHU LAA SHAREEKA LAH, LAHU -L-MULKU WA LAHU -L-HAMD, WA HUWA ALAA KULLI SHAIN IN QADEER, AAYIBUUN, TAA’IBUUN, AABIDUUN, Ll- RABBINAA HAAMIDUUN, SADAQA -L-LAHU WA’ADAH, WA NASARA ABDAH, WA HAZAMA -L-AHZAABA WAHDAH]. « Ko si oba kan ti o to lati fi ododo josin fun yato si Olohun Oba nikan soso, kò si orogun fun Un, Oun l’O ni akoso ati ope, Oun si ni Alagbara lori gbogbo nnkan, a pada de, a n ronupiwada Io si odo Olohun, a si n josin fun Olohun, a si n fi ope; fun Oluwa wa nikan, Olohun mu adehun Re; se, O si se aranse fun eru Re, O si segun awon ijo alaigbagbo I’Oun nikan soso >>.