Islam Azkar
Èdè Yorùbá
العربية
English
Français
Türkçe
Deutsch
Español
Indonesian
Kiswahili
haʊsə
Bahasa Melayu
Èdè Yorùbá
Yougandi
Gjuha shqipe
русский язык
Filipino
адыгэбзэ
Marnaou
සිංහල
فارسی
Azərbaycan dili
oʻzbekcha
tiếng Việt
Islam Azkar
1
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA JI
2
ADUA TI A O SE FUN ENI Tl O WO ASO TUNTUN.
3
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA N BO EWU RE
4
ADUA TI ENIYAN O SE NIGBA TI O BA FE WO ILE-IGBONSE TABI AYE YOWU TI O TI FE SE IGBONSE
5
ADUA T1 ENIYAN O SE NIGBA TI O BA N JADE KURO NI ILE-IGBONSE TABI IBIYOWU TI O TI SE IGBONSE
6
ADUA IBERE ALUWALA
7
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA FE JADE KURO NI ILE
8
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA FE WO ILE RE
9
ADUA TI ENIYAN O SE NIGBA TI BA N LO SI MASALASI
10
ADUA ATIWO MASALASI
11
ADUA ATIJADE NI MASALASI
12
AWON OHUN Tl ENIYAN YOO MAA WI NIGBA TI WON BA N PERUN
13
ADUA ISIRUN
14
ADUA TI ENIYAN YOO SE NI RUKU
15
ADUA TI ENIYAN O SE NIGBA TI O BA GBE ORI SOKE LATI RUKU
16
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA FI 0RI KANLE
17
ADUA TI ENIYAN O SE NIGBA TI O BA JOKOO LAARIN IFORIKANLE MEJEEJI
18
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA T’O BA FI ORI KANLE NI QKAN NINU AWON AYE TI A TI MAA N FI ORI KANLE NIGBA TI A BA N KEAL- OUR’AAN ALAPONLE
19
ATAAYA
20
ASALATU TI ENIYAN O SE FUN ANABI WA IKE ATI OLA OLOHUN K’O MAA BA A LEYIN ATAYA
21
ADUA TI ENIYAN O SE LEYIN ATAYA SIWAJU K1 O TOO SALAMA
22
ADUA TI ENIYAN O SE LEYIN IGBA TI O BA SALAMA ‘LEYIN IRUN’
23
ADUA IRUN ATITORO OORE [TITORO LODO OLOHUN PE KI O DARI ENI LO SIDI OHUN TI O LOORE LAYE ATI LORUN]
24
AWON ADUA ORU ATI TI OSAN
25
AWON ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA FE SUN
26
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O RA YIRA-PADA LORU
27
ADUA IBERU OJU-OORUN, ATI TI ENI TI BA N BE NINU ADANWO DIDAGBE
28
OHUN Tl ENI TI O BA LALA RI ABURU NI OJU-OORUN YOO SE NIGBA TI O BA JI
29
ADUA IDURO [AL-QUNUUT] TI IRUN WITR
30
ADUA TI ENIYAN YOO SE LEYIN TI O BA SALAMA NIIRUN WITR
31
ADUA AIBALE-OKAN ATI IBANUJE
32
ADUA IDAAMU
33
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA FE PADE OTA RE TABI ENI TI IJOBA N BE LOWO RE
34
ADUA ENI TI N BERU ABOSI ENI TI - AGBARA- IJOBA N BE LOWO RE
35
ADUA LORI OTA ENI
36
OHUN TI ENI TI BA N PAYA AWON KAN YOO WI
37
ADUA ENI TI IYEMEJI BA N SE IGBAGBQ RE
38
ADUA ATIRI GBESE SAN
39
ADUA TI ENI TI N SE IROYIROYI NINU IRUN ATI NINU KEWU KIKA LORI IRUN YOO SE
40
ADUA TI ENI Tl NNKAN KAN BA SORO FUN YOO SE
41
OHUN TI ENI TI O BA DESE KAN YOO WI ATI OHUN TI YOO SE
42
ADUA ATILE ESU ATI IROYIROYI RE JINNA
43
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI NNKAN TI KO FE BA SELE SI I, TABI NIGBA TI APA RE KO BA KA ORO ARA RE MO
44
BIBA ENI TI WON BIMO FUN YO ATI BI YOO TI DAHUN
45
OHUN TI A O FI MAA WA ISO FUN AWON OMODE
46
ADUA TI ENIYAN YOO SE FUN ALAARE NIGBA TI O BA BE E WO
47
OLA TI N BE FUN SISE ABEWO ALAARE
48
ADUA ALAARE TI KO SI IRETI ATISEMI FUN UN MO
49
OHUN TI A O NU ENI TI N POKAAKU
50
ADUA ENI TI ADANWO SE
51
ADUA TI A O SE NIGBA Tl A BA N PA OJU OKU DE
52
ADUA TI A O SE FUN OKU NIGBA TI A BA N KIRUN SI I LARA
53
ADUA TI A O SE FUN OKU TI O BA JE OMODE
54
ADUA IBANIKEDUN
55
ADUA TI A O SE NIGBA TI A BA N GBE OKU SINU SAARE
56
ADUA TI A O SE FUN OKU LEYIN TI A BA SIN IN TAN
57
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA BE AWON SAARE WO
58
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI AFEFE BA N FE
59
ADUA TI A O SE NIGBA TI ARA BA SAN
60
APA KAN NINU AWON ADUA ITORO OJO
61
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI OJO BA N RO
62
AL-DZKIR “IRANTI” TI ENIYAN YOO SE LEYIN TI OJO BA RO TAN
63
APA KAN NINU AWON ADUA TI A O SE NIGBA TI A BA N FE KI OJO O WAWO
64
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA RI OSU
65
ADUA TI ALAAWE YOO SE NIGBA TI O BA FE SINU
66
ADUA TI I SIWAJU OUNJE
67
ADUA TI ENIYAN YOO SE LEYIN OUNJE
68
ADUA TI ALEJO YOO SE FUN OLOUNJE TI O JE
69
ADUA TI ENIYAN YOO SE FUN ENI TI O BA FUN UN NI OMI MLU TABI ENI TI O FE FUN UN Nl OMI MU
70
ADUA TI ENIYAN YOO SE FUN AWON TI O SINU NI ILE WON
71
ADUA TI ALAAWE O SE NIGBA TI WON BA GBE OUNJE WA TI O SI KO LATI JA AAWE RE
72
OHUN TI ALAAWE O WI NIGBA TI ENIKAN BA BU U
73
ADUA TI ENIYAN O SE NIGBA TI O BA RI AKOKOJADE ESO
74
ADUA TI ENI TI O SIN O SE
75
OHUN TI A O SO FUN ALAIGBAGBO [KEFERI] NIGBA TI O BA SIN TI O SI DUPE FUN OLOHUN PE: AL-HAMDU LI-L-LAH
76
ADUA TI A O SE FUN ENI TI O GBEYAWO
77
ADUA TI ENI TI O GBEYAWO ATI ENI TI O RA ERANKO GUNGUN O SE
78
ADUA TI ENIYAN O SE SIWAJU KI O TOO BA IYAWO RE LO PO
79
ADUA IBINU
80
ADUA ENI TI O RI ENIKAN TI OLOHUN FI ADANWO KAN
81
OHUN TI ENIYAN YOO MAA WI NIBI TI O BA TI JOKOO
82
ADUA TI I PA ESE TI ENIYAN DA NIBI TI O BA TI JOKOO RE
83
ADUA TI ENIYAN O SE FUN ENI TI O BA SO FUN UN PE: [GAFARA -L-LAHU LAK] OLOHUN O FORI JIN O
84
ADUA TI O SE FUN ENI O SE DAADAA SI O
85
OHUN TI OLOHUN FI MAA N DAABO BO NI KURO LODO AD-DAJJAAL -OPURO OLOJUKAN-
86
ADUA TI O SE FUN ENI TI O BA SO FUN O PE: [INNEE UHIBBUKA FEE —L-LAH] MO FERAN RE NITORI OLOHUN
87
ADUA TI O SE FUN ENI TI O BA KOJU OWO RE SI O [PEKI O MU EYI TI O BA FE NINU EE]
88
ADUA TI ENI TI O YA ENIYAN LOWO YOO SE FUN ENI TI O YA LOWO NIGBA TI O BA SAN AN
89
ADUA IPAYA ISEBO SI OLOHUN “ASH- SHIRK"
90
ADUA TI ENIYAN YOO SE FUN ENI TI O BA SO FUN UN PE:[ BAARAKA —L-LAHU FEEK] OLOHUN O FUN O LALUBARIKA [OORE]
91
ADUA IKORIRA GBIGBA OHUN ASAN LASAN KAN GBO PE O LE MU KI IBI O SEYAN
92
ADUA ATIGUN OHUN GUNGUN
93
ADUA IRIN-AJO
94
ADUA ATIWO ILETO TABI ILU NLA
95
ADUA ATIWO OJA
96
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA RE OHUN TI O GUN
97
ADUA TI ONIRIN-AJO O SE FUN AWON TI YOO FI SILE
98
ADUA TI ENI TI N BE NILE O SE FUN ONIRIN-AJO
99
GBIGBE OLOHUN TOBI ATI SISE AFOMO FUN UN LORI IRIN-AJO
100
ADUA ONIRIN-AJO NI KUTU-IDAJI
101
ADUA TI ENIYAN O SE NIGBA TI O BA SO SI AYE KAN LORI AJO TABI NNKAN MIIRAN
102
IRANTI [AL-DZIKR] PIPADA LATI lRIN-AJO
103
OHUN TI ENI TI NNKAN IDUNNU TABI Tl NNKAN TI KO FE BA DE SI YOO WI
104
OLA TI N BE FUN SISE ASALATU [TITORO IKE ATI IGEI FUN ANABI WA IKE ATI OLA OLOHUN K’O MAA BA A
105
TITAN SALAMA [KIKI ARA ENI NI TI OLA] KA
106
BI A O TI DA ALAIGBAGBQ [KEFERI] LOHUN NIGBA TI O BA SALAMA SI WA
107
ADUA TI A O SE NIGBA TI AKUKO BA KO, ATI NIGBA TI KETEKETE BA KE
108
ADUA TI A O SE NIGBA TI A BA GBO GBIGBO AJA LORU
109
ADUA TI O SE FUN ENI TI O BA BU
110
OHUN TI MUSULUMI YOO WI NIGBA TI YOO BA YIN MUSULUMI EGBE RE
111
OHUN TI MUSULUMI YOO SO NIGBA TI WON BA FO O MO [TI WON BA YIN lN]
112
BAWO NI ENI TI O GBE HARAMI FUN HAJI TABI UMURA YOO TI MAA WI GBOLOHUN IJEPE [TELBIYYAH]
113
GBIGBE OLOHUN TOBI -ALLAHU AKBAR- NIGBA TI O BA DE IBI AL-HAJARU-L- ASWAD [OKUTA DUDU ].
114
ADUA TI ENIYAN YOO MAA SE LAARIN ORIGUN YAMAANI ATI TI OKUTA DUDU [AL-HAJARU-L-ASWAD]
115
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI O BA DURO LORI SAFA ATI MARWA
116
ADUA QJQ ARAFA
117
SISE IRANTI OLOHUN NI AL-MASH’ARU-L- HARAAM [NI MUZDALIFAH]
118
WIWI GBOLOHUN ALLAHU AKBAR NIGBA TI A BA N SO OKO KOOKAN NI IBUSQLOKO [NI MINA]
119
ADUA TI ENIYAN YOO SE NIGBA TI NNKAN KAN BA YA A LENU TABI O DUN UN NINU
120
OHUN TI ENI TI NNKAN IDUNNU BA SELE SI YOO SE
121
OHUN TI ENI TI N JE IRORA YOO WI
122
ADUA TI ENI TI N BERU KI OUN O MA FI OJU OUN BA NNKAN KAN JE YOO SE
123
OHUN TI ENIYAN O MAA WI NI ASIKO IJAYA
124
OHUN TI ENIYAN YOO WI NIGBA TI O BA FE DURAN TABI YOO GUNRAN
125
OHUN TI ENIYAN YOO WI LATI TI ETE AWON ESU ALAGBERE DANU
126
ITORO AFORIJIN ATI IRONUPIWADA
127
OLA TI N BE FUN GBOLOHUN “SUBHAANA -L-LAH” ATI “AL-HAMDU LI L-LAH" ATI “LAA ILAAHA ILLA -L-LAH” ATI “ALLAHU AKBAR”
128
BAWO NI ANABI WA IKE ATI OLA OLOHUN K’O MAA BA A TI I MAA N SE TESBEEH — AFOMO-
129
APA KAN NINU AWON OLOKAN-O-JOKAN OORE ATI AWON EKO TI O KARI